Ísíkẹ́lì 45:18 BMY

18 “ ‘Èyí yìí ní Olúwa Ọba wí: Ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù kìn-ín-ní ìwọ yóò mú akọ màlúù aláìlábàwọ́n kì o sì sọ ilé Ọlọ́run di mímọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 45

Wo Ísíkẹ́lì 45:18 ni o tọ