Ísíkẹ́lì 45:25 BMY

25 “ ‘Láàárin ọjọ́ méje àṣè náà, tí ó bẹ̀rẹ̀ ní ọjọ́ kẹẹdógún oṣù kéje, òun yóò tún pèsè nǹkan bí ti tẹ́lẹ̀, fún ọrẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, ọrẹ ẹbọ sísun, ọrẹ ẹbọ jíjẹ pẹ̀lú òróró.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 45

Wo Ísíkẹ́lì 45:25 ni o tọ