Ísíkẹ́lì 48:10 BMY

10 Èyí yóò jẹ́ ìpín ibi mímọ́ fún àwọn àlùfáà. Yóò jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́ ni gígùn ní ìhà àríwá, ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ìgbọ̀nwọ́ ni ìhà ìlà oòrùn, ó sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn ní ìhà gúsù. Ní àárin gbùngbùn rẹ̀ ní ilé fún Olúwa yóò wà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 48

Wo Ísíkẹ́lì 48:10 ni o tọ