Ísíkẹ́lì 48:11 BMY

11 Èyí yóò wà fún àwọn àlùfáà tí a yà sí mímọ́, àwọn Sódókítì tí wọn jẹ́ olóòótọ́ nínú sí sin mí, ti wọn kò sì sáko lọ bí ti àwọn Léfì ṣe se nígbà tí àwọn Ísírẹ́lì sáko lọ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 48

Wo Ísíkẹ́lì 48:11 ni o tọ