Ísíkẹ́lì 48:12 BMY

12 Èyí yóò jẹ́ ẹ̀bùn pàtàkì fún wọn láti ara ìpín ibi mímọ́ ilẹ̀ náà, ìpín tí ó jẹ́ mímọ́ jùlọ, tí ó jẹ́ ààlà agbégbé àwọn Léfì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 48

Wo Ísíkẹ́lì 48:12 ni o tọ