Ísíkẹ́lì 48:13 BMY

13 “Lẹ́gbẹ̀ẹ́ agbégbé àwọn àlùfáà, àwọn Léfì yóò pín ìpín kan tí ó jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn àti ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ìgbọ̀nwọ́ ní fífẹ̀. Gígùn rẹ̀ ní àpapọ̀ yóò jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹẹdọ́gbọ̀n (25,000) ìgbọ̀nwọ́, àti fífẹ̀ rẹ̀ yóò jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ìgbọ̀nwọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 48

Wo Ísíkẹ́lì 48:13 ni o tọ