Ísíkẹ́lì 48:17 BMY

17 Ilẹ̀ ìjẹ fún àwọn ẹran ọ̀sìn fún ìlú ńlá náà yóò jẹ igba àti àádọ́ta (250) ìgbọ̀nwọ́ ní ìhà gúsù, ìgbà àti ìgbà pẹ̀lú àádọ́ta (250) ìgbọ̀nwọ́ ní ìhà ìwọ̀ oòrùn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 48

Wo Ísíkẹ́lì 48:17 ni o tọ