Ísíkẹ́lì 48:18 BMY

18 Èyí tí ó kù ní agbégbé náà, tí ó jẹ́ ààlà ìpín ibi mímọ́, gígùn rẹ̀ yóò sì jẹ́ ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ìgbọ̀nwọ́ ní ìhà ìlà oòrùn àti ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ìgbọ̀nwọ́ ni ìhà ìlà oòrùn àti ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá (10,000) ìgbọ̀nwọ́ ní ìhà ìwọ̀ oòrùn. Ìpèsè rẹ̀ yóò fi kún oúnjẹ fún àwọn òsísẹ́ ìlú ńlá náà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 48

Wo Ísíkẹ́lì 48:18 ni o tọ