Ísíkẹ́lì 7:3 BMY

3 Òpin tí dé sí ọ báyìí n ó sì tú ìbínú mi jáde sí ọ, n ó dájọ́ rẹ gẹ́gẹ́ bí ìwà rẹ, ń ó sì san-an fún ọ gẹ́gẹ́ bí gbogbo ìwà ìríra rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 7

Wo Ísíkẹ́lì 7:3 ni o tọ