Ísíkẹ́lì 7:4 BMY

4 Ojú mi kò ní i dá ọ sì bẹ́ẹ̀ ni ń kò sì ní wò ọ́ pẹ̀lú àánú; ṣùgbọ́n ń ó san án fún ọ gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà rẹ àti gbogbo ìwà ìríra tó wà láàrin rẹ. Nígbà náà ní ẹ o mọ̀ pé èmi ni Olúwa.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 7

Wo Ísíkẹ́lì 7:4 ni o tọ