Ísíkẹ́lì 7:9 BMY

9 Ojú mi kò ní i dá ọ sí, ń kò sì ní wò ọ́ pẹ̀lú àánú; ń o san-an fún ọ gẹ́gẹ́ bí gbogbo ọ̀nà ìwà àti gbogbo ìwà ìríra tí wà láàrin rẹ. Nígbà náà ní ẹ o mọ̀ pé èmi Olúwa lo kọlù yín.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 7

Wo Ísíkẹ́lì 7:9 ni o tọ