Ísíkẹ́lì 8:10 BMY

10 Mo wọlé, mo sì rí àwòrán oríṣìíríṣìí ẹranko tí ń fà nílẹ̀ àti àwọn ẹranko ìríra àti gbogbo òrìṣà ilẹ̀ Ísírẹ́lì tí wọ́n yà sára ògiri.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 8

Wo Ísíkẹ́lì 8:10 ni o tọ