Nọ́ḿbà 1:16 BMY

16 Àwọn wọ̀nyìí ni wọ́n yàn nínú àwùjọ ènìyàn, olórí àwọn ẹ̀yà baba wọn. Àwọn ni olórí àwọn ẹbí Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 1

Wo Nọ́ḿbà 1:16 ni o tọ