Nọ́ḿbà 1:22 BMY

22 Láti ìran Símónì:Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ogún ọdún sókè, tí wọ́n lè lọ sójú ogun ni wọ́n kà, wọ́n sì to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 1

Wo Nọ́ḿbà 1:22 ni o tọ