Nọ́ḿbà 1:28 BMY

28 Láti ìran Ísákárì:Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ogún ọdún sókè tí wọ́n le lọ sójú ogun ni wọ́n to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 1

Wo Nọ́ḿbà 1:28 ni o tọ