Nọ́ḿbà 1:36 BMY

36 Láti ìran Bẹ́ńjámínì:Gbogbo ọmọkùnrin tí ọjọ́ orí wọn jẹ́ ogún ọdún sókè ni wọ́n to orúkọ wọn lẹ́yọ kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ ẹbí àti ìdílé wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 1

Wo Nọ́ḿbà 1:36 ni o tọ