4 Kí ẹ mú ọkùnrin kọ̀ọ̀kan tí ó jẹ́ olórí ìdílé rẹ̀ láti ràn yín lọ́wọ́.
5 Orúkọ àwọn ọkùnrin tí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ nìyí:Láti ọ̀dọ̀ Rúbẹ́nì, Élísúrì ọmọ Ṣédéúrì;
6 Láti ọ̀dọ̀ Símónì, Ṣélúmíélì ọmọ Ṣúrísáddáì;
7 Láti ọ̀dọ̀ Júdà, Násónì ọmọ Ámínádàbù;
8 Láti ọ̀dọ̀ Íssákárì, Nítaníẹ́lì ọmọ Ṣúárì;
9 Láti ọ̀dọ̀ Ṣébúlúnì, Élíábù ọmọ Hélónì;
10 Láti ọ̀dọ̀ àwọn sọmọ Jósẹ́fù:láti ọ̀dọ̀ Éfraimù, Elisámà ọmọ Ámíhúdì;Láti ọ̀dọ̀ Mánásè, Gámáélì ọmọ Pedasúrù;