Nọ́ḿbà 1:45 BMY

45 Gbogbo ọmọkùnrin Ísírẹ́lì tó jẹ́ ọmọ ogún ọdún (20) sókè, tó sì lè lọ sójú ogun ni wọ́n kà gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 1

Wo Nọ́ḿbà 1:45 ni o tọ