8 Láti ọ̀dọ̀ Íssákárì, Nítaníẹ́lì ọmọ Ṣúárì;
9 Láti ọ̀dọ̀ Ṣébúlúnì, Élíábù ọmọ Hélónì;
10 Láti ọ̀dọ̀ àwọn sọmọ Jósẹ́fù:láti ọ̀dọ̀ Éfraimù, Elisámà ọmọ Ámíhúdì;Láti ọ̀dọ̀ Mánásè, Gámáélì ọmọ Pedasúrù;
11 Láti ọ̀dọ̀ Bẹ́ńjámínì, Ábídánì ọmọ Gídíónì;
12 Láti ọ̀dọ̀ Dánì, Áhíésérì ọmọ Ámísádáì;
13 Láti ọ̀dọ̀ Áṣérì, Págíélì ọmọ Ókíránì;
14 Láti ọ̀dọ̀ Gáádì, Élíásàfu ọmọ Déúélì;