22 Àwọn ìpín tó wà ní ibùdó Éfúráímù ló tún kàn lábẹ́ ọ̀págun wọn. Elisámà ọmọ Ámíhúdì ni ọ̀gágun wọn.
Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 10
Wo Nọ́ḿbà 10:22 ni o tọ