Nọ́ḿbà 10:33 BMY

33 Wọ́n sì gbéra láti orí òkè Olúwa ní ìrìn ọjọ́ mẹ́ta. Àpótí Ẹ̀rí Olúwa ń lọ níwájú wọn fún gbogbo ọjọ́ mẹ́ta yìí láti wá ibi ìsinmi fún wọn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 10

Wo Nọ́ḿbà 10:33 ni o tọ