Nọ́ḿbà 11:1 BMY

1 Àwọn ènìyàn ń ṣe àròyé nípa wàhálà wọn sí etíìgbọ́ Olúwa. Ìbúnú Olúwa sì ru sókè nígbà tí ó gbọ́ àròyé yìí, Nígbà náà ni iná jáde láti ọ̀dọ̀ Olúwa bọ́ sí àárin wọn, ó sì run àwọn tó wà ní òpin ibùdó.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 11

Wo Nọ́ḿbà 11:1 ni o tọ