Nọ́ḿbà 11:21 BMY

21 Ṣùgbọ́n Mósè sọ pé, “Mo wà láàrin ọgbọ̀n ọ̀kẹ́ ènìyàn (600,000) ni ìrìnkirì, ó sì sọ pé, ‘Èmi ó fún wọn ní ẹran láti jẹ fún oṣù kan gbáko!’

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 11

Wo Nọ́ḿbà 11:21 ni o tọ