Nọ́ḿbà 11:23 BMY

23 Olúwa sì dá Mósè lóhùn pé, “Ọwọ́ Olúwa ha kúrú bí? Ìwọ yóò ri nísinsin yìí bóyá ọ̀rọ̀ tí mo sọ yóò ṣẹ tàbí kò ni í ṣẹ.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 11

Wo Nọ́ḿbà 11:23 ni o tọ