Nọ́ḿbà 15:26 BMY

26 A ó dárí ji gbogbo ìjọ ènìyàn Ísírẹ́lì àti àwọn àlejò tí ń gbé ní àárin wọn nítorí pé ní àìròtẹ́lẹ̀ ni wọ́n sẹ ẹ̀ṣẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 15

Wo Nọ́ḿbà 15:26 ni o tọ