Nọ́ḿbà 15:40 BMY

40 Nígbà náà ni ẹ ó gbọ́ran láti pa gbogbo òfin mi mọ́, ẹ ó sì jẹ́ mímọ́ sí Ọlọ́run yín.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 15

Wo Nọ́ḿbà 15:40 ni o tọ