Nọ́ḿbà 15:9 BMY

9 Ẹni náà yóò mú ọ̀dọ́ akọ màlúù náà wá pẹ̀lú ọrẹ ohun jíjẹ, ìdá sí mẹ́ta nínú mẹ́wàá òṣùwọ̀n ìyẹ̀fun ìyẹ̀fun kíkúná tí a fi ìdajì òṣùwọ̀n òróro pò.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 15

Wo Nọ́ḿbà 15:9 ni o tọ