Nọ́ḿbà 16:1 BMY

1 Kórà ọmọ Íṣárì, ọmọ Kóhátì, ọmọ Léfì àwọn ọmọ Rúbẹ́nì: Dátanì àti Ábírámù, àwọn ọmọ Élíábù, àti Ónù ọmọ Pélétì mú ènìyàn mọ́ra.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 16

Wo Nọ́ḿbà 16:1 ni o tọ