Nọ́ḿbà 16:29 BMY

29 Bí àwọn ènìyàn yìí bá kú bí gbogbo ènìyàn ti ń kú, bí ìrírí wọn kò bá sì yàtọ̀ sí ti àwọn ènìyàn yóòkù, a jẹ́ pé kì í ṣe Olúwa ló rán mi.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 16

Wo Nọ́ḿbà 16:29 ni o tọ