Nọ́ḿbà 16:42 BMY

42 Ṣùgbọ́n nígbà tí gbogbo ìjọ ènìyàn péjọ lòdì sí Mósè àti Árónì, níwájú àgọ́ ìpàdé, lójijì ni ìkúùkù bolẹ̀, ògo Olúwa sì fara hàn.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 16

Wo Nọ́ḿbà 16:42 ni o tọ