Nọ́ḿbà 17:10 BMY

10 Olúwa sọ fún Mósè pé, “Mú ọ̀pá Árónì padà wá ṣíwájú Ẹ̀rí, láti fi pamọ́ gẹ́gẹ́ bí àmìn fún àwọn ọlọ̀tẹ̀. Èyí ó sì mú òpin bá kíkùn sínú wọn sí mi, kí wọn kí ó má baà kú.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 17

Wo Nọ́ḿbà 17:10 ni o tọ