Nọ́ḿbà 18:20 BMY

20 Olúwa sọ fún Árónì pé, “O kò ní ní ogún nínú ilẹ̀ wọn bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kò ní ní ìpín láàrin wọn, Èmi ni ìpín àti ogún rẹ láàrin àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 18

Wo Nọ́ḿbà 18:20 ni o tọ