Nọ́ḿbà 19:19 BMY

19 Ọkùnrin tí ó mọ́ ni kí ó bu omi wọ́n àwọn ènìyàn aláìmọ́ ní ọjọ́ kẹ́ta àti ọjọ́ kéje, ní ọjọ́ kéje ó gbọdọ̀ wẹ ara rẹ̀ mọ́, Ẹni tí a wẹ̀ mọ́ gbọdọ̀ fọ aṣọ rẹ̀ kí ó sì wẹ̀ pẹ̀lú omi, ní ìrọ̀lẹ́ ọjọ́ náà yóò mọ́.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 19

Wo Nọ́ḿbà 19:19 ni o tọ