Nọ́ḿbà 19:21 BMY

21 Èyí jẹ́ ìlànà láéláé fún wọn.“Ọkùnrin tí ó wọ́n omi ìwẹ̀nùmọ́ náà gbọdọ̀ fọ aṣọ rẹ̀ àti ẹnikẹ́ni tí ó fi ọwọ́ kan omi ìwẹ̀nùmọ́ yóò di aláìmọ́ títí di ìrọ̀lẹ́.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 19

Wo Nọ́ḿbà 19:21 ni o tọ