Nọ́ḿbà 19:7 BMY

7 Lẹ́yìn náà, Àlùfáà gbọdọ̀ fọ aṣọ rẹ̀, kí ó sì wẹ ara rẹ̀ pẹ̀lú omi lẹ̀yìn náà ó lè wá sínú àgọ́. Ṣùgbọ́n yóò jẹ́ aláìmọ́ títí ìrọ̀lẹ́.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 19

Wo Nọ́ḿbà 19:7 ni o tọ