Nọ́ḿbà 2:18 BMY

18 Ní ìhà ìlà oòrùn ni ìpín Éfúráímù yóò pa ibùdó rẹ̀ sí lábẹ́ ọ́págun rẹ̀. Olórí Éfúráímù ni Élíṣámà ọmọ Ámíhúdì.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 2

Wo Nọ́ḿbà 2:18 ni o tọ