Nọ́ḿbà 2:24 BMY

24 Gbogbo ènìyàn tí a yàn sí ibùdó Éfúráímù, gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn, àpapọ̀ iye wọn jẹ́ ẹgbàá mẹ́rìnléláàdọ́ta-ó-lé-ọgọ́rùn-ún (108,100). Àwọn ni yóò jáde sìkẹ́ta.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 2

Wo Nọ́ḿbà 2:24 ni o tọ