Nọ́ḿbà 2:34 BMY

34 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì se gbogbo ohun tí Olúwa pa láṣẹ fún Mósè, báyìí ni wọ́n ṣe pa ibùdó lábẹ́ ọ̀págun wọn, bẹ́ẹ̀ náà sì ni wọ́n ṣe jáde, oníkálùkù pẹ̀lú ẹbí àti ìdílé rẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 2

Wo Nọ́ḿbà 2:34 ni o tọ