Nọ́ḿbà 20:24 BMY

24 “Árónì yóò kú. Kò ní wọ ilẹ̀ tí mo fi fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, nítorí ẹ̀yin méjèèjì ṣe àìgbọ́ràn sí òfin mi níbi omi Méríbà.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 20

Wo Nọ́ḿbà 20:24 ni o tọ