Nọ́ḿbà 21:22 BMY

22 “Jẹ́ kí a kọjá ní orílẹ̀ èdè rẹ. A kò ní kọjá sí inú oko pápá tàbí ọgbà tàbí mu omi láti inú kànga. A máa gba òpópónà náà ti ọba títí tí a ó fi la ilẹ̀ rẹ kọjá.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 21

Wo Nọ́ḿbà 21:22 ni o tọ