Nọ́ḿbà 21:35 BMY

35 Wọ́n sì pa á, pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ àti gbogbo àwọn ọmọ ogun rẹ̀, wọn kò fi ẹnìkankan sílẹ̀. Wọ́n sì gba ìní ilẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 21

Wo Nọ́ḿbà 21:35 ni o tọ