Nọ́ḿbà 22:31 BMY

31 Nígbà náà Olúwa sí ojú Bálámù, ó sì rí ángẹ́lì Olúwa tí ó dúró ní oju ọ̀nà pẹ̀lú idà rẹ̀ tí ó fàyọ. Ó sì tẹ orí rẹ̀ ba.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 22

Wo Nọ́ḿbà 22:31 ni o tọ