Nọ́ḿbà 23:14 BMY

14 Ó sì lọ sí pápá Ṣóímù ní orí òkè Písígà, ó sì kọ́ pẹpẹ méje síbẹ̀ ó sì fi akọ màlúù àti àgbò kọ̀ọ̀kan rúbọ lórí pẹpẹ kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 23

Wo Nọ́ḿbà 23:14 ni o tọ