Nọ́ḿbà 23:17 BMY

17 Nígbà náà ó lọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀ ó sì báà tí ó dúró sí ẹ̀gbẹ́ ẹbọ rẹ̀ pẹ̀lú àwọn ìjòyè Móábù. Bálákì sì béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ pé, “Kí ni Olúwa wí?”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 23

Wo Nọ́ḿbà 23:17 ni o tọ