Nọ́ḿbà 23:24 BMY

24 Àwọn ènìyàn dìde bí abo kìnnìún;wọ́n dìde bí i kìnnìúntí kì í sinmi títí yóò fi pa ìkógún jẹtàbí mu ẹ̀jẹ̀ ẹni tí ó fi ara pa.”

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 23

Wo Nọ́ḿbà 23:24 ni o tọ