Nọ́ḿbà 25:6 BMY

6 Nítòótọ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọkùnrin Ísírẹ́lì sì mú obìnrin Mídíánì wá ṣíwájú ojú Mósè àti gbogbo ìpéjọ ti Ísírẹ́lì wọ́n sì ń sunkún ní àbáwọlé Àgọ́ Ìpàdé.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 25

Wo Nọ́ḿbà 25:6 ni o tọ