Nọ́ḿbà 25:8 BMY

8 Ó sì tẹ̀lé arákùnrin Ísírẹ́lì yìí lọ sínú àgọ́. Ó sì fi ọ̀kọ̀ gún àwọn méjèèjì ní àgúnyọ láti ara ọkùnrin Ísírẹ́lì àti sí ara obìnrin náà. Nígbà náà ni àjàkálẹ̀-àrùn lórí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sì dúró;

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 25

Wo Nọ́ḿbà 25:8 ni o tọ