Nọ́ḿbà 26:57 BMY

57 Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Léfì tí a kà nínú wọn gẹ́gẹ́ bí ìdílé wọn:ti Gáṣónì, ìdílé àwọn ọmọ Gáṣónì;ti Kóhátì, ìdílé àwọn ọmọ Kóhátì;ti Mérárì, ìdílé àwọn ọmọ Mérárì.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 26

Wo Nọ́ḿbà 26:57 ni o tọ