Nọ́ḿbà 3:25 BMY

25 Iṣẹ́ àwọn ìdílé Gásónì nínú Àgọ́ Ìpàdé ni pé àwọn yóò máa tọ́jú àgọ́, ìbòrí àgọ́, aṣọ títa ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé,

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 3

Wo Nọ́ḿbà 3:25 ni o tọ