Nọ́ḿbà 31:23 BMY

23 Ohunkóhun tí ó lè la iná ni kí ẹ̀yin ó mú la iná, nígbà náà ni yóò jẹ́ mímọ́. Ṣùgbọ́n ẹ ó ò fi omi ìyàsímímọ́ sọ ọ́ di mímọ́. Àti gbogbo ohun tí kò lè la iná kọjá ni kí a mú la inú omi.

Ka pipe ipin Nọ́ḿbà 31

Wo Nọ́ḿbà 31:23 ni o tọ